Rajinikanth | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Shivaji Rao Gaekwad 12 Oṣù Kejìlá 1950 Bangalore, Mysore State, India (now in Karnataka, India) |
Ibùgbé | Chennai, Tamil Nadu, India |
Orílẹ̀-èdè | Indian |
Iṣẹ́ | Film actor, producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1975–present |
Olólùfẹ́ | Latha Rajinikanth (1981–present) |
Àwọn ọmọ | |
Àwọn olùbátan | see Rajinikanth family tree |
Awards | Padma Vibhushan (2016) Padma Bhushan (2000) |
Shivaji Rao Gaekwad (bìi ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kejìlá Ọdún 1950) wọ́n t́n mọ̀ọ́ sí Rajinikanth, jẹ́ òṣère eré ìtàgé Orílẹ èdè Indian tí ó ń ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ fiimu Tamil. Ó ti kópa nínú eré àwon Bollywood, Telugu, Kannada, Malayalam , Hollywood ati eré ìtàgé ní ède Bengali. Ó b`ẹr`ẹ eré ìtàgé ṣíṣe nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ olùdarí ọk`ọ p`ẹlú ilé iṣẹ́ ọk`ọ wíwà Bangalore. Ní ọdún 1973, ó darapọ mọ́ ilé `ẹkọ Madras Film Institute lati gba oyè diploma nínú eré ìtàgé ṣíṣe